1. SE se ninu mi dun, Ayo nla kun okan mi, Kristi lo pe mi sinu ogo, Ki yio fi mi sile lai. 2. Larin ota larin idamu, Je k’itansan ogo mi han, Ki’ Ife Re ran mi lo ‘dopin, Ki nle ma je olori. 3. Kristi Baba to pe mi, Jo mase fi mi sile, Ayo nla to fun mi, Ki nle lo dopin aiye mi. Amin