1. MA se yemeji, ma se wehin, Oniyemeji k’ yio debite, Mimo niwaju Baba, Ta fi didan osumare se loso, Ni ‘joba ti Orun. 2. Fi okan mimo, ife mimo, Igbagbo, Ireti Mimo, Sin Oluwa, Olorun Eleda, Aiyenlo s’opin, Awon tire si nto lehin larin, Iyemeji laibikita. Amin