1. Ona to ‘lorun ngba soro, Lati se Ise Re, Ona Re enikan ko mo, Awamaridi ni. 2. Alaigbagbo won yio sina, Won ko ‘se Oluwa, Sugbon awa to gb’Oluwa gbo, A ki yio pofo laiye. Amin