BO ti wu Baba lo nse ise Re, Awamaridi ni lawon ise Re, Ari pase Re lori Okun, Orun, Osupa pelu awon ‘rawo ri, Won wa riri. Amin