HYMN 5

1. K’awa elese yiwa pada,

   Jesu yio s’okale sinu wa o,

   K’awa elese yiwa pada,

   Jesu yio sokale sinu wa o.

   Nibo la o duro de Jesu?

   Tawa yio fi ri?

   N’ile esin la wa o ri Jesu.


2. Nibo la o duro de Jesu?

   Tawa yio fi ri?

   N’ile esin la wa o ri Jesu.

   Bi Jesu ba de, k’awa wole,

   St. Michael yio sokale sinu wa o.

   T’aba wole tan, Michael ba de,

   K’awa elese wa toro idariji,

   T’aba wole tan, Michael ba de,

   K’awa elese wa toro idariji.	Amin 

English »

Update Hymn