HYMN 489

1.  MO mbo, emi Jesu mbo,

     Emini Oluwosan,

     Baba mi Io fun mi,

     Fun ododo nla kan.


2.  Wakati mi ti de,

     Wakati Baba mi,

     Aiye yio si ri,

     Ododo nla kan ni.


3.  Awa elese de,

     Awa elese de,

     Lati wa gba ‘dariji,

     Lati wo orun rere.  Amin

English »

Update Hymn