HYMN 487

1.  AGBARA mbe ninu eje odo Agutan,

     Agbara mbe ninu eje odo Agutan,

     Agbara mbe ninu eje odo Agutan,

     Ninu eje Jesu.


2.  Iwosan mbe ninu eje odo Agutan,

     Iwosan mbe ninu eje odo Agutan,

     Iwosan mbe ninu eje odo Agutan,

     Ninu eje Jesu.


3.  Igbala mbe ninu eje odo Agutan,

     Igbala mbe ninu eje odo Agutan,

     Igbala mbe ninu eje odo Agutan,

     Ninu eje Jesu.


4.  Isegun mbe ninu eje odo Agutan,

     Isegun mbe ninu eje odo Agutan,

     Isegun mbe ninu eje odo Agutan,

     Ninu eje Jesu.


5.  Aiye mi mbe Iowo Re Kristi Oluwa,

     Aiye mi mbe Iowo Re Kristi Oluwa,

     Aiye mi mbe Iowo Re Kristi Oluwa,

     O mbe n’owo Jesu.  Amin

English »

Update Hymn