1. MO feri O, Olorun,
Mo feri O, Olorun
Mo feri Olorun, ninu
ayo nla.
2. Sanu fun wa, Olorun,
Sanu fun wa, Olorun,
Sanu fun wa,
Ka le w’ole Ogo.
3. Segun fun wa, Olorun,
Segun fun wa, Olorun,
Segun fun wa, ka le
wole Ogo. Amin