1. LASANLASAN ni nwon se O ara,
Lasanlasan ni nwon mbe,
Ada ko ma ran Omo
Kristi O laiye
Lasanlasan ni nwon mbe.
2. Omo enia ngberaga
s’Oba Oluwa,
Omo enia nsefe o,
S’Oba Oluwa,
Lasanlasan ni nwon mbe,
3. Owo 0 ma ko imole,
Ti mbe loke Orunlaiye o,
Lasanlasan laiye ma wa o,
Lasanlasan laiye ma wa o. Amin