1. ANGELI Oluwa, E sokale ninu iponju wa, Angeli Oluwa, E sokale ninu iponju wa. 2. Ajagun segun ode Orun, E sokale ninu iponju wa, Angeli Oluwa, E sokale ni mimo julo. 3. Awon Oso, awon Aje, Awon onisegun, olorisa won yi wa ka, Angeli Oluwa, E sokale ninu iponju wa. Amin