1. PESE fun wa o Baba,
Chorus: Pese fun wa O.
2. Olodumare Ire lawa
gbojule.
Chorus: Pese fun wa O.
3. Olodumare Ire lawa
gbojule.
Chorus: Pese fun wa o.
4. Orisun ayo ti nso
eso iye.
Chorus: Pese fun wa o.
5. Oba ti ngbin ti awa
nka.
Chorus: Pese fun wa o. Amin