HYMN 426
El Beraca, Beredi Eli,
Oluwa mi, Oba, Olubukun Ikore,
Wa ro Ojo Ibukun Mana Re sori wa loni,
Jehovah Elyon, Oluwa Olola giga julo,
Wa fi Ola ainipekun Re, gbe wa ga,
Gbomo Re ga, larin ajoyo wa t’oni,
El Morijah ‘luwa Oba Olupese,
Jowo wa pese fun gbogbo aini wa,
Ki gbogbo iro ‘nu wa le di ayo,
Ati ki gbogbo egan wa le di ogo,
Enyin Angeli Mimo t’Orun,
Ba wa ko orin yi i,
Ka wa le mu ohun rere lo sile wa,
Kristi alase laiye l’orun,
Sami si fun wa,
Amin, Amin, Amin, Amin, Amin, Amin. Amin
English »Update Hymn