1. Wa pelu wa, sure fun wa, oba Mimo Se ri ‘bukun Re s’ori wa, Ka ma bisi, ka ma re si, ni Ijo Mimo K’Alleluya le j’orin wa. 2. Michael Mimo, gbe’da soke ka le bori Gbogbo ota Ijo Mimo K’o ko kehin le w’aiye mo lase Kristi, Ka le jumo ke Hossanah. 3. Ka boyun bi, kawon agan towo b’osun Ka ma rago, ka ma pose Ka je sekun, l’alafia ninu ayo nla. Ki Iye, Igbala je pin wa. Amen