HYMN 387

1.	Emi ba legberun ahon,

	Fi yin Olugbala,

	Ogo Olorun oba mi,

	Isegun ore re, 

Chorus:	A bi ko seun fun o,

	A o ma se fun mi,

	Eje re se fun,

	Eje re se fun mi.


2.	Jesu to soro mi dayo,

	O mu banuje tan,

	Orin ‘yin lenu elese,

	Iye ati ilera.

Chorus:	A bi ko seun fun o,

	A o ma se fun mi,

	Eje re se fun,

	Eje re se fun mi.


3.	Baba mi at’Olorun mi,

	Fun mi ni ‘ranwo Re,

	Ki nle ro ka gbogbo aiye,

	L’ola oruko re,

Chorus:	A bi ko seun fun o,

	A o ma se fun mi,

	Eje re se fun,

	Eje re se fun mi.


4.	O korin odi gbohun Re,

	A foju ri gbala,

	Oniro binuje yo y’ayo,

	Ara e ho fayo. 

Chorus:	A bi ko seun fun o,

	A o ma se fun mi,

	Eje re se fun,

	Eje re se fun mi. Amin

English »

Update Hymn