O ye wa, k’a fope f’Oluwa, Awa ti mbe ni aiye, Jowo gbo ohun awa omo Re, Gege bo ti gbo ti isiwaju, Awa elese nke pe e o O, Jowo gbohun wa. Amin.