1. E yin Akorin n’jo Mimo, E ko rin Oluwa s’oke, Pelu awon angeli l’oke Orun, E jumo ko orin yin didun. 2. Eyin Ayanfe, ni Ijo Mimo, E gbe Oluwa ga l’oke Orun, Pelu awon Angeli l’oke Orun, Enyin Baba na, l’ori ite Re. Amin