1. E yo, e yo, e yo, e yo, Ijo Mimo ninu ogo na. 2. Ayo ti Baba gbe fun wa, Ijo Mimo ninu ago Re. 3. Ogo, Ogo, Ogo, Ogo, Ni fun l’Orun loke Orun. 4. Ayo ati iteriba, Laiye yi yio ri ogo Re. 5. Ijo Mimo, E sin, e sin, Esin ni yio gba nyin lo s'orun. 6. Iteriba at’ esin Yio gbe yin dodo Baba. Amin