HYMN 286

1.	IGBA ironu de,

	Yara si iye ainipekun,

Chorus:	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Awon oniyemeji,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Aje ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Oso ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo.


2.	Asan lohun aiye,

	Ati awon ohun ekun re,

Chorus:	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Awon oniyemeji,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Aje ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Oso ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo.


3.	Mimo, Mimo, Mimo,

	Ki ise ti aiye yi nikan, 

Chorus:	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Awon oniyemeji,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Aje ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Oso ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo.


4.	Wakati na ti de,

        Sise ninu ife Mimo Baba 

Chorus:	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Oko kehin ti de,

	Kristi npe elese,

	Awon oniyemeji,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Aje ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo,

	Oso ko le woko na,

	Nwon yio gunle sebute ofo. 	Amin

English »

Update Hymn