1. Igbala de loni, Enyin Ijo Mimo, E gbo bi ipe tin dun, Ipe Odo aguntan 2. Ipe na dun kikan, E mase jafara, Sa sala f’emi Re Ka koko to koja. 3. Olugbala na de, Lati ra wa pada E kanu fese yin, Ti nda eru ba yin. Amin