HYMN 282
1. BABA wa, Omo sokale,
Lori ‘te Mimo Re,
Lati mu ibukun ati
Ogo f'omo Re
2. Baba orun mbe ninu ayo,
Pelu awon Angeli,
Jesu Kristi, Baba wa
nyo pelu won.
3. E ke Hossanah si Oba wa,
Oluwa Olubukun,
T’ombe ninu Tempili re
Mimo, O Si nyo.
4. Baba wa Orun sokale sire,
Pelu awon Ogun Orun
Awon Si busi ayo
fun Ijo Mimo yi.
5. E ke Halleluya , s'Oba wa
Awa Elese yi.
Nitoripe Emi Oluwa
mbe lotito.
6. Ka fope fun Olorun wa,
Fun ise Re gbogbo
Iyanu ni ise Re,
lori awa eda.
7. 'Jo Celestial, Ijo Mimo
T'Emi oluwa bukun,
Nitori ese aiye po,
l'ase mu yi wa.
8. Kawa elese yiwa pada,
T’ori idajo wole,
lo ri awon eni ibi,
l'emi o se yi. Amin
English »Update Hymn