1. AWA n’Ijo Mimo Aladura, Ijo Mimo dara, Jesu Baba wa f’ohun rere sile, Inu wa si dun Halleluya. 2. Awa nyo ninu Jesu, n’Ijo Mimo, Jesu mbe lehin wa, Ohun gbogbo t’awa mbere lowo Re, O si ti fun wa Halleluya. 3. Awa ni Ijo Mimo loke Orun, Ijo Mimo mbe, Awon Angeli nyo peluwa, Ara wa si ti ya Halleluya. Amin