1. WA sodo Mi, Wa sodo Mi Wa sodo Mi, Lati gba ore-ofe. 2. Iye ni temi, Anu ni temi Mimo ni temi Mimo l’awon Angeli nko. 3. ko ese rewa, Wa si ljo Mimo, Anu mbe lodo Jesu Kristi. Amin