1. Ojo agbara a,
Ojo Agbara a,
T’awon Angeli nyo,
Ojo agbara a, Ojo agbara a,
T'awon Angeli nyo,
2. E ke Hossannah,
E ke Hossannah,
S’Oba Oga Ogo,
Inu wa dun pupo,
Inu wa dun pupo,
Fun Ojo Mimo yi. Amin