1. AGBARA na owole,
Ijo Mimo, e yo,
Isegun na O ti wole,
Ijo Mimo, e yo.
2. Ojo ayo I’ojo oni je,
Lodo Baba Mimo,
E yo, e yo, e yo,
E yo ninu Kristi.
3. Halleluya Halleluya,
Nisegun Ijo yi je,
Halleluya Halleluya,
N'isegun Ijo yi je. Amin