1. Emi Mimo
sokale wa O,
KO wa fun wa
Iagbara.
2. Jesu Oluwa o,
sokalewa O,
KO wa fun wa
lagbara.
3. Adaba Mimo, sokale wa o,
Ko wa fun wa
lagbara.
4. Maleka Mimo
sokale wa o,
Ko wa fun wa
lagbara.
5. Ogun orun Mimo,
sokale wa o,
Ko wa fun wa
lagbara.
6. Emi Mimo, Sokale wa o
Ko wa fun wa
lagbara. Amin