1. JESU ni iyo aiyeraiye,
Jesu ni iyo aiyeraiye,
Jesu ni Kristi na:
ninu Ijo Mimo,
Ti yio bori aiye.
2. Jesu ni imole aiyeraiye,
Jesu ni Imole aiyeraiye,
Jesu ni Oba kan na
loni, lola
Ti yio bori aiye. Amen