HYMN 214

1.  OGO ni fun Alagbara nla,

     Ogoni fun Ologo julo,

     Ogo ni fun Olubukun nla,

     Ogo ni fun Baba.


2.  F’iyin fun Alagbara nla,

     F’iyin fun Ologo nla,

     F’iyin fun Olubukun julo,

     F'iyin fun Baba. Amin

English »

Update Hymn