1. BABA a Baba a, Larin wakati yi,
Baba a Baba a. Larinwakati yi,
Chorus: F'ogo Re fihan aiye o Oluwa.
K'aiye le mo wipe,
K’aiye le mo wipe,
Ire lo ran mi ni ‘se.
2. Jesu u Jesu u Tire ni isegun,
Jesu u Jesu u, Tire ni igbala
Chorus: F'ogo Re fihan aiye o, Oluwa etc.
3. Aiye ko fe iwosan ti Jesu
Aiye ko fe igbala ti Jesu
Chorus: F’ogo Re fihan aiye o Oluwa. etc. Amin