E YINOluwa Halleluya, Eyin Oluwa Halleluya, Eleda Orun, lyanu ni ise Re gbogbo Halleluya, Oba awon Oba Halleluya, Oluse ohun gbogbo Halleluya, E wa, k’ajo sin ninu ljoMimo Halleluya, E wa k'asin pelu iteriba, K’asin pelu ibowo, Osi tij’Oba Halleluya, Lori Satani Halleluya, EKe Halleluya,enyin araiye. Amin