HYMN 183

1.  IYE! Iye! Iye! ni ti wa,

     Oluwa Olufe,

     O fe ife iye si wa.


2.  Lat'orun Mimo,

     nwon nko orin ayo,

     Hossanah, Ogo la o ma ko,

     Ni 'nu Ijo Mimo. Amin

English »

Update Hymn