HYMN 18

Dariji emi omo Re Baba,

Mo wa jewo ese mi fun O,

Dariji emi omo Re Baba,

Dariji emi omo Re Baba,

Nipa ahon mo ti se si O o,

Nipa irin mo ti se si O o,

Nipa esin mo ti se si O o,

Nipa iwa mo ti se si O o,

Mo wa jewo ese mi fun o,

Dariji emi omo Re Baba,

Dariji emi omo Re Baba. Amin

English »

Update Hymn