HYMN 16

1.	Idariji ese lantoro,

	Idariji ese lantoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa dariji ese jiwa, 


2.	Anu Re lawa ntoro,

	Anu Re lawa ntoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa ranu Re si wa.


3.	Iwosan Re la ntoro,

	Iwosan Re la ntoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa ran wosan si wa.


4.	Igbala Re la ntoro,

	Igbala Re la ntoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa fi ‘gbala fun wa.


5.	Ibukun Re la ntoro,

	Ibukun Re la ntoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa ran ‘bukun si wa.


6.	Igbega Re la ntoro,

	Igbega Re la ntoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa ran ‘gbega si wa.


7.	Abo Re lawa ntoro,

	Abo Re lawa ntoro,

	Baba Mimo, Omo Mimo,

	Ko wa d’abo Re bowa.	Amin.

English »

Update Hymn