1. Jesu wa, oluwa olugbala, Si lekun anu re fun wa K’awon ogun orun Re wole wa, Halleluyah ni orin wa Halleluyah, Halleluyah, Halleluyah mbe lenu wa. 2. Maleka mimo oga Ogun O mbe lenu ‘bode orun Lati ba gbogbo emi esu wi Ka le riye gba lojo na, Jehovah mimo mbe Jehovah mimo mbe Jehovah mimo mbe 3. Kristi wa duro lori apata O npe wa ka duro lor’apata Enit’ o ba duro lori re Ni yio ri, Kristi ni kehin Jesu wa Mimo ni Kristi wa Mimo ni E o ri Jesu nikehin. Amin