HYMN 153

1.	Mo nlo si Jerusalemu,

	 Mo nlo si Jerusalemu,

	Mo ti f’owo mi ko‘we ohun rere,

	Emi ko ni pada mo.


2.	Mo nlo si nu Ijo Mimo,

	 Mo nlo si nu Ijo Mimo,

	Mo ti f’owo mi ko‘we ohun rere,

	Emi ko ni pada mo.	Amin

English »

Update Hymn