Mimo, Mimo, l’Olorun wa, O boju Re wo sara awa elese Iyanu nise Re gbogbo, Mimo, l’Olorun wa Mimo, Pelu iteriba l’awon angeli nkorin Orin iyin didun, Baba, Omo, Emi Mimo, Ore-ofe Re gbogbo po, Lori Ijo Mimo. Amin