1. Iwa rere mo nt’oro fun yin, Enyin Woli mi gbogbo, E ko iwa ilara kuro, Ka le sunmo Oluwa. 2. Jihmarta Mimo lo njise yi, Loni k’eyin ma yo, ma yo, Ke we gbogbo ese okan yin mo, Ka le sunmo Kristi. Amin