HYMN 129

 
Hossanah l’atorun wa,

Pelu orin ayo,

Olugbala yio pada wa,

Lai ko ni ireti,

E fogo f’Oluwa,

E f’ogo f’Oluwa,

Awon angeli kun f’ayo, pelu iyin.	Amin

English »

Update Hymn