HYMN 128

1.	Ara, e ba mi ka lo,

	Pade Oluwa mi o,

	Ara, e ba mi ka lo,

	Pade Oluwa mi o,

	Ni Bethlehemu,

	Ni Ilu ayo,

	Ni Bethlehemu,

	Ni I	lu ayo.



2.	Awon Angeli njo,

	Awon Maleka nyo,

	Awon Angeli njo,

	Awon Maleka nyo,

	Nwon nke Hossanah,

	S’Omo Dafidi,

	Nwon nke Hossanah,

	S’Omo Dafidi.	Amin

English »

Update Hymn